NAHCON pin ijoko Hajji ọdun 2023 fun awọn arin irin ajo to wa ni awọn ilu, ni ijọba, ni awọn ile iṣẹ, ati bẹẹ bẹẹ lọ


Ajọ Hajji ti Naijiria (NAHCON) ti ṣẹ ikede ijoko Hajji ti ọdun 2023 fun ilu mẹrindinlọgọrun iranlọwọ ọkọ/abẹwẹ/ififunni ẹlẹsin ajo, pẹlu FCT ati awọn ologun lẹyin ipari ipade awọn Exco tọ yi ọjọ pinpin yẹn, gẹgẹ bi gbolohun oṣiṣẹ.

Pinpin yẹn wa nipasẹ NAHCON ni lana pinpin ijoko/iho ti Saudi Arabia. Ni Abuja, Moussa Ubandawaki ti n ṣẹ Iranlọwọ Oludari Iranlọwọ ati awọn atẹjade NAHCON fi ṣẹ akiyesi/ṣẹ akọsilẹ pe awọn pinpin ijoko jẹ: Abia (mẹtalelaadọta), Adamawa (igba le ni ọgọrun mẹfa le ni mọkandinladọrun), Anambra (ookandinlogoji), Bauchi (ẹgbẹẹdogun le ni ọọgurun le ni mejilelọgbọn), Bayelsa (aarundinlogoji), Benue (igba le ni mẹrindinlogoji), Borno (igba le ni ọgọrun meje le ni aarundinlogoji), Cross Rivers (mẹrindinladọrin), Delta (mẹrinleladọrin), Nassarawa (ẹgbẹrun le ni ẹẹdẹgbẹta le ni mẹtadinladọrin), Niger (ẹẹdẹgbẹta le ni ọgọrun le ni aarindinladọrin), Ogun (ẹgbẹrun le ni ọgọrun le ni ookandinlogoji), Ondo (irinwo le ni ẹẹrindinlogoji), Ọṣun (ẹgbẹrun le ni mẹrinlaadọta), Ọyọ (ẹgbẹrun ati irinwo le ni mọkanlelogoji), Yobe (ẹgbẹrun le ni ọgọrun mẹsan le ni mẹjidinladọrin), Ebonyi (ọgọrun le ni mẹtadinlogun), Ẹdo (igba le ni mẹrinleladọrin), Ekiti (igba le ni mẹtadinigba), Ẹnugu (ogoji), FCT (ẹgbẹẹdogun le ni ẹẹdẹgbẹta le ni ogun), Gombe (igba le ni ọgọrun mẹta le ni ookan), Imo (ọgbọn), Jigawa (ẹgbẹrun le ni ẹẹdẹgbẹta le no aarundinlọgbọn), Kaduna (ẹẹdẹgbẹta le ni ọgọrun mẹsan le ni mejidinladọrun), Kano (ẹẹdẹgbẹta le ni ọgọrun mẹsan le ni meji), Katsina (ẹgbaaji le ni ọgọrun mẹsan le ni ẹẹtala), awọn ajagun (ẹẹdẹgbẹta le ni marundinladọta), Kẹbbi (ẹgbaaji le ni ọgọrun mẹjọ le ni mọkanleladọrin), Kwara (ẹgbẹẹẹdogun le ni igba le ni mọkandinlogun), Eko (ẹgbẹẹẹdogun le ni ẹẹdẹgbẹta le ni mẹfadinlọgọrin), Plateau (ẹgbẹrun le ni ọgọrun mẹsan le ni mẹrinlelọgọrin), Rivers (aadọta), Ṣokoto (ẹẹdẹgbẹta le ni ẹẹdẹgbẹta le ni mẹrin), Taraba (ẹgbẹrun le ni ẹẹdẹgbẹta le ni adọrun), ati Zamfara (ẹẹgbẹdogun le ni mẹtalelọgọrin).

Related: 

NAHCON Allocates 2023 Hajj Seats to States Pilgrims, Govt. Agencies, Others

DONATE

https://selar.co/1rqb

For Advert Inquiries
Tele/+234 7036309859
E-mail: themuslimvoiceng@gmail.com

For News/Article
E-mail: themuslimvoiceng@gmail.com

Have any Question or Comment?

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

error: Content is protected !!
Chat With Our Agent!