Iwọn 7.8 gbigbọn ilẹ pa to ẹgbẹfa eniyan, to si ṣẹ ijamba si ẹgbẹrun eniyan ni guusu ila-ọọrun ilu Turkey ati ariwa oorun ilu Syria ni owurọ ọjọ Ajẹ ti n ṣẹ ọjọ kẹfa, oṣu keji, ọdun 2023.
Awọn apakan meji ti opo epo gaasi ni Hatay, ilu kan ni Turkey bibu ṣẹlẹ bi abajade ti iparun gbigbọn ilẹ ti o kọlu guusu ila-ọọrun ilu Turkey ati ariwa oorun ilu Syria.
Awọn alaṣẹ ilu Turkey ti pinu lati da ipese ti gaasi duro si nọmba kan ti agbegbe to sumọ awọn apọju tawọn gbigbọn ilẹ, gẹgẹ bi iroyin ijabọ Ikhlas Turkish.
Bakanna, iwọn gbigbọn ilẹ 7.5 miran tu lu Turkey ni agbegbe Elbistan ti Turkey ti n ṣẹ ekun Kahramanmaras ni ago kan lọ lu iṣẹju merinlelogun ọsan ni akoko agbegbe yẹn.
Nigba ti ni kikun iye ti ibajẹ ti gbigbọn ilẹ yẹn fa ma fi ara rẹ han ni awọn ọjọ to n bọ, awọn seismologist sọ pe gbigbọn ilẹ yi jẹ ọọkan ninu awọn gbigbọn ilẹ tọ ti gbalẹ nilu Turkey.
Related:
Earthquakes in Turkey and Syria- Report
Editors’ Picks
DONATE
For Advert Inquiries
Tele/+234 7036309859
E-mail: themuslimvoiceng@gmail.com
For News/Article
E-mail: themuslimvoiceng@gmail.com
One comment on “Gbigbọn ilẹ ni Turkey ati Syria- Ijabọ”
[…] Gbigbọn ilẹ ni Turkey ati Syria- Ijabọ […]